
Klement Ola-Daniels – Molólúwa Lyrics
Artist: Klement Ola-Daniels
Song: Molólúwa
A
Ẹ′rù ò bà mí
E e e e a
0 seconds of 0 secondsVolume 0%
Àyà ò f’omì
Rárá o o
Ẹ′rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Molólúwa o, ye ye
Àyà kò f′omì
Àyà kò f′omì
Àyà kò f’omì
Moní Bàbá kan, ye ye
Ẹ′rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Ẹ′rù kò bà mí
Moní Jésù
Alágbára ni
Àyà kò f’omì
Àyà kò f′omì
Àyà kò f’omì
Molólúwa o
Bàbá Awímáyẹhun
Asọ’rọ′ má gbàgbé ni, ye
Ẹ′rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Ẹ′rù kò bà mí
Moní Jésù L’olúwa, a
Àyà kò f′omì
Àyà kò f’omì
Àyà kò f′omì
Ọ’rẹ’ mi ni, ye a
Ẹ′rù kò bà mí
Ẹ′rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Molólúwa o
Ọ′rẹ’ mi ni, yes
Àyà kò f′omì
Àyà kò f’omì
Àyà kò f′omì
Bàbá mi ni o, a
Ọba Awímáyẹhun
Asọ’rọ’ Mátàsé ni, a
A
When I called
Òun jẹ mí
When I cried
Òun gbọ mi
When in pains
Òun rí mi
When in need
Òun rí mi
He came to earth to set me free
Laid his life to make me king
Washed my sins on Calvary with his blood
Alágbàwí ẹ′dá
Agbani-Lágbàtón ni
Yes
Ẹ′rù ò bà mí
Àyà kò f’omì
Molólúwa o, yes
Àyà kò f′omì
Ẹ’rù ò bà mí
Moní Bàbá kan
Alágbára ni
Ọba Awímáyẹhun
Asọ′rọ’ má gbagbé ni, ye
Ẹ′rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Molólúwa o, ye ye
Àyà kò f′omì
Àyà kò f′omì
Àyà kò f’omì
Ọ′rẹ’ mi ni, ye
Ẹ′rù kò bà mí
Ẹ’rù kò bà mí
Ẹ′rù kò bà mí
Molólúwa o
Ọ’rẹ’ mi, yes a a a
Àyà kò f′omì
Àyà kò f′omì
Àyà kò f’omì
Moní Bàbá kan
Ọba Awímáyẹhun
Asọ′rọ’ Mátàsé ni
Find more lyrics at https://dcslyrics.com


Disclosure: As an Amazon Associate and an Apple Partner, we earn from qualifying purchases
U.S. Bunny – A Seguir Adelante
Clauneck Sixxx – Vlad Tepes
Klement Ola-Daniels Lyrics – Molólúwa
Please support our site by sharing it.
And please follow our site to get the latest lyrics for all your favourite songs.
Release Year: 2020