Debra Crown-Olu – KORIN SI OLUWA

Debra Crown-Olu KORIN SI OLUWA

Debra Crown-Olu – KORIN SI OLUWA Lyrics

Artist: Debra Crown-Olu
Song: KORIN SI OLUWA

Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti
O pọ′ li ogo:
Ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu
ADVERTISING

Sinu okun pupa.
OLUWA li agbara ati orin mi,
On li o si di ìgbala mi:
Eyi li Ọlọrun mi, emi o si fi ìyin fun u;

Kabioyesi mo se iba re
Emi o kọrin si OLUWA,
Emi o kọrin si OLUWA, nitoriti
O pọ’ li ogo:

Ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu
Sinu okun pupa.
Oluwa, li asà fun mi; ogo mi;
Olugbe ori mi soke.

Emi fi ohùn mi kigbe si Oluwa,
O si gbohùn mi lati òke mimọ′ rẹ’ wá.
Emi o kọrin si OLUWA,
Oba to ‘n be ninu orun

Gbega mi o le sai gbega titi lai.
O ran omo ni se fayati
Gbega mi o le sai gbega titi lai.
You are bigger than the Biggest

Olowogbogboro ti ′n gba omo re lofin
A se kabiesi re eladumare tewogbope
(Omo egbala gbo in so ke).
Oba to ti wa o, k′ aye to wa

Ti si tun ma wa nigba ti aye ko no si mo
Mo ni, Oluwa n’ be bi ti ati Jo
A wa la o sin baba bi ta ti jo.
Bri:

Ologun li OLUWA; OLUWA li orukọ rẹ′.
Ọwọ’ ọtún rẹ li ogo ninu agbara:
Ọwọ′ ọtún rẹ fọ’ ọtá tútu.
Emi o kọrin si OLUWA,

Mo korin hallelujah
Mo ke hallelujah
Ona to di ti la o
Oluwa la ona ni bi to ko so na

Ona to di ti la o
Ogo oluwa won la ye mi
Find more lyrics at https://dcslyrics.com

You can purchase their music thru
DCSLyrics.com Amazon Music    DCSLyrics.com Apple Music
Disclosure: As an Amazon Associate and an Apple Partner, we earn from qualifying purchases

KORIN SI OLUWA Lyrics – English Translation

I will sing unto the LORD, because
You’re so glory:
He is overthrowed
Adverting

Into a red sea.
The Lord has my strength and my song;
He also has become my salvation:
This is my God, and I will give him;

KABEFE I WAFE YOU
I will sing unto the LORD,
I will sing unto the LORD, because
You’re so glory:

He is overthrowed
Into a red sea.
O Lord, in me a shield; my glory;
Population up my head.

I cry out to the Lord my voice,
He answered me from his holy heart ‘.
I will sing unto the LORD,
The Obama is’ kept in heaven

Be proud of me you can have to say forever.
You help baby in search
Be proud of me you can have to say forever.
You are Bigger Than The Biggest

Excess of miserapy ‘
We Kabeesi your Kabiab Contacts
(The Monite Elustry List).
The Obama has, k ” existence

Is still when the world does not know
I have, Lord n ​​’urge as of and dance
We Serve the Father as to be danced.
BRI:

The Lord is a military; The Lord is his name. ‘
The right hand is glorious in power:
His right hand broke ‘the enemy.
I will sing unto the LORD,

I Kiss Halleljah
I cut the Halleljah
The Way Becoming La You
Lord is path in the way of

The Way Becoming La You
I understand my Lord’s
Find more lyrics at https://dcslyrics.com

Debra Crown-Olu Lyrics – KORIN SI OLUWA

Please support our site by sharing it.
And please follow our site to get the latest lyrics for all your favourite songs.

Please support the artist and us by purchasing your favourite music thru our Amazon Music and Apple Music links 🙂

You can purchase their music thru
DCSLyrics.com Amazon Music    DCSLyrics.com Apple Music
Disclosure: As an Amazon Associate and an Apple Partner, we earn from qualifying purchases

Release Year: 2021